Word |
# |
Sentence |
ogbon |
5 |
Lati opin orun 19th, awon onimo mathimatiki bi Frege teju si fifi mathimatiki se ogbon, loni oro nipa ogbon pin si meji: ogbon mathimatiki (formal symbolic logic; ogbon ami-idamo) ati eyi ti a mo loni bi ogbon onimoye. |
ìsopọ̀ |
4 |
Agbára àwọn ìsopọ̀ kẹ́míkà jẹ́ orísirísi; àwọn "ìsopọ̀ líle" bíi àjọfagbáradìmú tábí íónì wà àti àwọn "ìsopọ̀ dídẹ̀" bíi ìbáṣepọ̀ ipoméjì sí ipoméjì, agbara ìfọ́nká London àti ìsopọ̀ háídrójìn. |
jẹjẹrẹ |
4 |
Ati wò lápapọ̀ pé wọ́n lè dẹ́kun ìdá 70 ti kòkòrò jẹjẹrẹ abẹ́ obìnrin, ìdá 80 ti kòkòrò jẹjẹrẹ ihò-ìdí, ìdá 60 ti kòkòrò ojú ara obìnrin, ìdá 40 ti kòkòrò jẹjẹrẹ ojú ìta ara obìnrin, àti bóyá kòkòrò jẹjẹrẹ ẹnu. |
kíkékúrú |
4 |
Àwọn ìpìlẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin tó wà nínú DNA ni adẹnínì (kíkékúrú sí A), sitosínì (kíkékúrú sí C), guanínì (kíkékúrú sí G) àti timínì (kíkékúrú sí T). |
Byron |
4 |
George Gordon Byron, 6th Baron Byron, later George Gordon Noel, 6th Baron Byron, FRS (22 January 1788 – 19 April 1824), to gbajumo bi Lord Byron (Iba Bairon), je akoewi ara Britani ati eni asiwaju ninu Iseromansi. |
ìdìpọ̀ |
4 |
Ìdìpọ̀ yìí ní ìtòrò ìdìpọ̀ méjì, bẹ́sìni ìjúwe rẹ̀ ṣe é pè bíi ìdìpọ̀ ẹ̀mejì tàbí bíi ìsopọ̀ ìdìpọ̀ ẹlẹ́ktrónì ìkan-méjì àti two ìdìpọ̀ ẹlẹ́ktrónì méjì-mẹ́ta. |
pààlà |
4 |
Ní apá ìlà-oòrun, wọ́n bá ilú Sàbọmì àti Igbotu pààlà, ní apá ìwọ̀-oòrùn ìlú Ọ̀rẹ̀ àti Odìgbó pààlà, ní àriwá tí wọ́n sì ba ìlú Okìtìpupa-Ìdèpé àti Ìgbòbíní pààlà nígbà tí gusu wọ́n bá ìlú Ọ̀mì pààlà. |
npè |
4 |
Ni awọn ere, Mario (akọkọ ti a npè ni Ogbeni Video ati ki o si Jumpman) gbọdọ gbà a ọmọbinrin ninu ipọnju ti a npè ni Pauline (akọkọ ti a npè ni Lady), lati kan omiran ape ti a npè ni Ketekete Kong. |
matrix |
4 |
Ní ìmọ̀ ìṣirò, Hurwitz matrix, tàbí Routh-Hurwitz matrix, ní ìmọ̀ ẹ̀rọ, ìdúróṣinṣin matrix, jẹ́ ètò square matrix gidi tí wọ́n ṣètò ẹ̀ pẹ̀lú àwọn coeficient polynomial gidi. |
ìyí |
4 |
Nítorípé ìyí onírúiyepúpọ̀ aláìjẹ́ òdo gbọ́dọ̀ jẹ́ ìyí ọ̀rọ̀ tó ní ìyí tótóbijùlọ, onírúiyepúpọ̀ ìgbékalẹ̀ọ̀rọ̀ òkè yìí ní ìyí éjì. |
adé |
4 |
Ó gbé adé kan lọ́wọ́, ó súre fún Àjàpadá, ó sì sọ fún Àjàpadá pé, ‘mo fi adé yìí jì ọ́’ Mo fi adé jì ọ́, ni ó wá di ‘Déjì’tí o jẹ́ orúkọ oyè ọba ìlú Àkúrẹ́, gẹ́gẹ́ bí ẹni tí Òdùduwà fi adé jì2. |
Ọgbẹ́-inú |
4 |
Ọgbẹ́-inú Buruli (tí a tún mọ̀ sí Ọgbẹ́-inú Bairnsdale, Ọgbẹ́-inú Searls, tàbí Ọgbẹ́-inú Daintree ) jẹ́ àrùn àkóràn èyítí ó má a nwáyé nípasẹ̀ Mycobacterium ulcerans. |
kòtò |
4 |
Ọkọ̀ tí wọ́n fi ń gbẹ́lẹ̀ tí ó bá ara rẹ̀ nínú kòtò tí ó sì dáwọ́ gbígbẹ rẹ̀ dúró Òfin kòtò àkọ́kọ́ tàbí Òfin kòtò jẹ́ òwe tí ó sọ wípé "tí o bá ba ara rẹ nínú kòtò, kí o maa ṣe gbẹ́ ẹ síwájú síi". |
Olè |
4 |
Olè di Olè náà, ògbójú Olè náà, ògbójú alágbára Olè náà pẹ̀lú ìwo, abbl. |
gberingberin |
4 |
Papa gberingberin yi ko se foju ri sugbon ohun ni un fa ini pataki gberingberin kan: agbara la ti fa awon eroja gberingberin ferro bi irin be ni o si un fa mora tabi sun sohun awon gberingberin miran. |
Yemen |
4 |
Saleh teletele je Aare Orileolominira Arabu Yemen (Ariwa Yemen) lati 1978 titi de 1990, nigbato bo sipo bi alaga Igbimo Aare Orileolominira Yemen (unified Yemen). |
Singapore |
4 |
Singapore Press Holdings Ltd., Singapore, ISBN 9789814266246 ( ; ojoibi 3 July 1924) je oloselu are Singapore to je Aare ile Singapore kefa. |
ààrùn |
3 |
Aarun ẹdọ A (tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí àkóràn ààrùn ẹ̀dọ̀) jẹ́ líle ààrùn àkóràn ti ẹ̀dọ̀ tí kòkòrò àkóràn ààrùn ẹ̀dọ̀ A fà (HAV). |
Longe |
3 |
Ada pe re a si maa je "Longe" - Idi niyi ti owe yoruba kan se so wipe "Ewu nbe loko Longe, Longe funrara re ewu ni". |
oselu |
3 |
Akoso, o dabi lati ti tẹ si okun, awọn ifilelẹ ti awọn atako oselu aṣọ mu nipa Raila Odinga, ani bi o ati Raila ti ti gun-duro oselu ọta ati fun igba pipẹ dabi enipe julọ išẹlẹ ti ti oselu ore. |